Oje ede Yoruba ta n lo lati salaye
wi pe onikaluku lo mo iru eniyan to le dojuko lati se nkan maje-aye-o-gbo si
lowo. Bi apeere o see se ki owo da eniyan, kii se gbogbo eniyan la le dojuko
lati basiri wa tabi lati yawa lowo. Iru eniyan ta a le se nkan basiri si lowo
ni a yibon idi si.
The turkey knows whom to direct its fart
to.
No comments:
Post a Comment