Iyan o, Iyan o
Iyan funfun lele
Iyan t'o wewu egunsi
T'o wo sokoto isapa
To de fila ede
Iyan o, Iyan o
Kokoro funfun ona ofun
Paapoo a-bodo-sagidi,
Oba ninu ounje
A-bu-s'owo kiribiti,
Ore agbe, ota oyinbo
A-je-n-je-tunje
A-je pantete, ete
Aje mu aya rerin-in ofofo
A-je digbo loko wi
Osupa abe iti
A-ran-ma-dele-ole
👍🙌🙌🙌
ReplyDelete