Monday, 15 August 2016

IPA OGBE NI NSAN: (THE WOUND LEFT BY A CUTLASS MAY HEAL)



     Ipa ogbe ni nsan je owe Yoruba ti ipari re je, ipa ohun kii san. A maa n lo lati salaye tabi kilo fun eniyan wi pe egbo tabi ogbe ti oro maa n mu kii ni wosan lailai. Oun ni Yoruba se boti won wi pee yin lohun to ba bo sile, ko see sa mo.

     Oro la gbara pipo, oro lafi nyo obi lapo oun naa lo tun nmu ida jade ninu ako. Owe yi mumi ranti isele kan to wa laarin awon loko laya kan ti igbeyawo won koju odun kan lo nigba naa. Olorun bere sini gbe owo oko soke, oun ri jaje. O bere si nig be nkan irese. Sugbon gege bi opolopo igbeyawo tuntun se maa n koko la ijikoja ni ibere. Bee naa ni awon naa la ti won koja.
     Oro sebi gbonmi si omi o too laarin awon mejeeji nijokan. Nigbatii oko iyawo nsoro si iyawo lori oun to se ti oun kofe, to sii nso fun un wi pe iwa igberaga re poju pe ko ni rele, fara ti iyawo maa dahun o ni se nitori awon nkan to ti ngbese won yi ni o se ngun oun gara gara, wi pe ti inu ba bi oun si, gbogbo nkan adaru fun debi ti won o ni ri ojutu re layelaye.
     Bi enipe arabinrin yi fi ase senu ni, ose yen gangan ni won da oko duro nibise, nitori owo nla kan ti o sonu ninu ofiisi re. won fi olopaa gbe, won gbese le gbogbo oun to ti fi owo de mole ki won le taa lati di owo naa pada. Aanu olorun lofi bo ninu oran ti ko mowo ti ko mese yi sugbon ni gba to maa fib o ninu wahala naa ko si dukia kookan fun un mo, nse lo se se beret un ni wa se kiri.
     Eyin eniyan mi, oro yi lotu igbeyawo awon loko laya yi ka. Ti onikaluku fon da gbe.

No comments:

Post a Comment