Birom je eya kan lori le ede Naijiria
lati ipinle Plateau. Awon ti o n so ede yi to milionu kan leniyan. Won sunmo Hausa
sugbon won kii se Hausa. Won tankale si ibile merin (Ariwa jos,guusu Jos,
Barkin ladi ati Ri yom. A tun ri won ni guusu Kaduna.
Ede Birom ni awon ara Birom maa nso. Won
maa n se odun Nzem – Berom lodoodun ni osu keta tabi ikerin.
Ise agbe ati ise eran dida ni o wopo
laarin won. Won feran ise ode eran pipa debi wi pe eyi to poju ninu oruko ti
won maa n fun awon omo won je oruko eranko. Bi apeere pam, Dung, chuwang.Oruko
eniyan ni“Bot” o si tumo si "opolo". Oruko oye oba awon Birom ni Gbong Gwom Jos.
No comments:
Post a Comment