Tuesday, 2 August 2016

ILE YORUBA




      Apa iwo oorun Afrika ni orile ede Naijiria, Benin ati Togo ni awon Yoruba wa. Won tedo si ife ni odun 400 BCE. Gbogbo ile Yoruba bo si abe isakoso biritiko ni odun 1862. Ile Yoruba wa ninu awon ilu to di orile ede Naijiria ni odun 1914.
     Ni pa ti asa, ile ife ni olu ilu Yoruba. Ni pa tie to oselu Ibadan ni olu ilu Yoruba. Ni pa ti oro aje, eko ni olu ilu Yoruba.
     Awon ilu to wa la be ile Yoruba ni ipinle Oyo, Osun, Ogun, Ondo, Ekiti, Eko, Kwara, Edo,Oueme, Plateaus, Collines, Donga, Borgu, Plateaux ati Centrale.
     Oba ni o nse olori ilu ati ijoba ni ile Yoruba. Awon ologboni ni won ma nse asofin. Awon oloye ni won maa nran oba lowo pelu isakoso re. Balogun ni asaaju ogun ni ilu. Eto ikaniyan (ti a fo yewo mo) ti odun 2015 so wi pe gbogbo omo Yoruba je milioni marun le laadota, 55 million.
     Awon esin meta ti o fi di mule nile Yoruba ni esin musulumi, esin kirisiteni ati esin abalaye.
     Ile Yoruba ni awon igbo nla nla ati awon ile titeju. Awon ilu oloke naa wa , won wa ni Ekiti, paapaa julo ni Effon ati Okemesi. Awon isosi le omi (waterfall) si wa kaakiri ile Yoruba, bi awon to wa ni Olumirin, Arinta, Effon ati bee bee lo.
     Ori oke idanre ni ibi to ga julo ni ile Yoruba, o ga niiwon mita 1050 .Ile Yoruba ni opolopo odo nla ati awon isan omi ti o la awon ilu koja. Ona meji ni awon odo wonyii doriko, Awon kan dori ko guusu sinu osa, ti osa naa si n da omi tire sinu okun. Awon kan si n san lo si ariwa, lo sinu odo nla Naija. Awon odo to nsan lo si gusu ni odo Osse ni Edo, odo Osun ti o nsan sinu osa to wa ni Lekki, odo Ogun to nsan sinu Osa- Eko. Awon odo bii Mono, Oba, Owera, Erinle, ati Yewa nsan sinu alaiye Badagiri (creek). Odo Okpara nsan sinu osa to wa ni Porto- Novo.
     Awon ipinle to wa ni Orile ede Naijiria to je ti Yoruba ni Oyo, Osun, Ogun Kwara, Ondo, Ekiti ati Eko, apakan kogi ati Edo.
     Awon ilu to je ti Yoruba ni Orile ede Bene ni Oueme, Plateau,Collines, Tchaourou ti Borgu, Bassila ti Dorga, Ouinhi ati Zogbodomey ti Zou, ati Kandi ti Alibori.
    Apa Yoruba to wa ni Togo ni Ogou ati Est- Mono to wa ni PLateaux ati Tchamba to wa ni Central.
      Orisirisi awon igi lo wa ni ile Yoruba lara won ni Iroko,Afara,Sapele, Obeche Maogani ati bee beelo. Won tun ni igi owo ni ile Yoruba awon bii koko, roba, ati obi.
     Oduduwa ni awon Yoruba gba gegebi baba nla won. Ilu (ti o ni ijoba) merin din logun ni a tara oduduwa ati awon omo re da sile. Lai ka awon ilu kereje kereje mo won.
     Oye idile ni Oye oba ni ile Yoruba.

12 comments:

  1. aiseesoft-blu-ray-player-crack
    is a powerful media player for PC that supports all video formats without any codec and directly loads the disc. So, get here the simple playback option and need a click to take the screen snapshot.
    freeprokeys

    ReplyDelete
  2. bitdefender-total-security-crack can be an expansion of this window operating-system security offer deal. This app includes system protection bundles, such as optimization. For example, instance,
    new crack

    ReplyDelete
  3. Thanks for the great message! I really enjoyed reading
    you could be a good writer. Evil Alvzis notes blog and testament
    will finally come back later. I want to support
    keep writing well, have a nice weekend!
    avocode crack
    advanced systemcare pro crack
    screenhunter pro crack
    advanced system optimizer crack

    ReplyDelete
  4. Hey! This is my first visit to your blog.
    We are a collection of volunteers starting with one
    a new project in the community in the same niche.
    Your blog has provided us with useful information to work with. YOU
    did a fantastic job!
    minitool power data recovery
    driverpack solution crack
    fileviewpro crack
    luxion keyshot pro crack

    ReplyDelete
  5. Yes, I'd want to ask whether you know of an online community that covers the same issues as this article.
    I'd love to be involved.
    of a community where people are able to learn from others who share their interests and knowledge.
    Please share your thoughts with us if you have any. That's so kind of you!
    revo uninstaller crack
    polarr photo editor pro crack
    snagit crack
    driver genius crack

    ReplyDelete
  6. Oh, God! Wonderful friend article! Thanks. However, I have problems with your RSS feed.
    I don't understand why I can't join. Does anyone have the same problems with RSS? Who knows the answer, could you answer me? Thanks!!
    adobe bridge crack
    wondershare filmora crack
    ashampoo burning studio crack
    myriad pdftomusic pro crack

    ReplyDelete
  7. I am very impressed with your post because this post is very beneficial for me and provide a new knowledge to me.
    killsquad crack
    little nightmares 2 crack
    Styx: Shards of Darkness Crack

    ReplyDelete
  8. Hello! This is my first visit to your blog.
    We are a collection of volunteers from one
    a new project in the community in the same nice.

    anytrans crack
    fl studio
    website auto traffic generator ultimate
    carbon copy cloner
    endnote crack
    bluestacks crack

    ReplyDelete
  9. I guess I am the only one who comes here to share my very own experience guess what? I am using my laptop for almost the past 2 years.

    adina-system crack



    nch-photopad-image-editor Crack



    zemax-opticstudio Crack



    redcrab-calculator-plus Crack



    wondershare-mobiletrans Crack

    ReplyDelete
  10. I am very impressed with your post because this post is very beneficial for me and provides new knowledge to me.
    iTop VPN
    ESET Smart Security Premium
    Switch Sound File Converter

    ReplyDelete