Ejire ara isokun
Edunjobi
Omo edun tii sere
Ori igi reterete
O fese mejeeji be sile
Alakisa
O sa lakisa do ni gbaaso
Gbajumo omo tii gba dobale
lowo baba,
Tii gbakunle lowo
mama to bii lomo
Wirinwirin loju orogun
Ejiworo loju iyaare
No comments:
Post a Comment