Lojokan,
baba olowo kan mu omo re okunrin rin irinajo lati lo fi bi awon talaka se n gbe
igbe aye won han an. Won lo ojo die ninu oko eniyan kan ti won ri gege bi
apeere talaka.
Nigbatii won ta jode, baba naa bi omo re
wi pe omo mi ba woni oti ri irinajo wa si?
“Nje o
ri bi awon talaka ti n gbe le aye won?” baba re e bi.
“ O dara
lopo, baba.”
“ Nje
ori bi awon talaka ti n gbe? Baba re bii.
“ be e
ni baba “ omo re dahun.
“So fun
mi kilo ko ninu irinajo yii?. Baba re e bi?
Omo naa
dahun wi pe “mori wi pe awa ni aja kan won ni meran. Awa ni adagun omi to nsan
wo inu ogba ewebe wa, awon si ni ogbara omi ti sisan re ko do pin.
Awa ngbe lori ile kekere, awon ngbe lori
papa ti fife re koja wi won. Awa ni awon omo odo to nsin wa, sugbon awon nsin
elomiran.
Awa nra ounje, awon ngbin ounje won.
Awa mo ogiri yi dukia wa ka lati dabobo wa,
awon ni awo ore to ndabobo won.
Oro pe
si je lenu baba yi.
Omo re
wa so wi pe “Esee baba mi fun bi eti ti fi han mi bi ati je oto si to.
No comments:
Post a Comment