An lo gbolohun yi lati kilo fun eniyan wi pe eniyan ki i se oun to
ju agbara re lo. Nitori alaaso kan kii sere eti omi. Bi apeere iya agbalagba to
lomo kan soso laye, ti ko si si oko mo, to ti koja nkan osu sise, ko gbodo so
wi pe ki omokunrin kan soso tohun bi mura oju ogun lati lo ja fun iluwon.
A one – eyed person does not attempt
standing somer saults.
No comments:
Post a Comment