Tuesday, 16 August 2016
Oriki awon Onikoyi
Yanbiolu, Eso Ikoyi, Omo Olooto Egi
Yanbiolu, omo apo ti i segun fona,
Eruwa gboko ma sungbe
Omo Agbon to tilu Igbon wa
Eleegba omo adipelemo nijo ti a rogun Oba
Aroni ku sedi omo Agbon Telewusi
Obe iwo lo o jagun
Ajuwon, iwo lo o tafa,
Ajuwon Ajaka, e ma reko ana wa ya fogun kogun o roun je
Aroni ku lai jaya ote
Ajaa iweyin lo mu Eso wumi
Ogun ojoojumo lo mu ile won su mi i lo
Ikoyi omo agbon-tu-bele ija
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
ogun ajaiweyin lomukoyi wunmi ogun ojoojumo lomule baba eni suni, omo gbanhin, omo gbanhin,omo gbanhingbanhin to so mo esin lehin orun.
ReplyDeletee kaare
ReplyDelete