YORUBAOLOJI
Tuesday, 16 August 2016
Kaka ki nbi egbaa obun
Kaka ki n bi egbaa obun
Ma kuku bi okansoso oga
Ma fi yan araye loju
Mo roun gberaga
Se okansoso araba
Kii segbe egbaa osunsun
Omo to jafafa kansoso
Kii sogba igba irunbi omo
Akuku ibi san se radarada
Ka ku lomode ko yeni
San ju ka dagba atoroje lo
2 comments:
Funmi Adeliyi
1 November 2021 at 03:39
Awesome! Please can you help me translate this to English.
Reply
Delete
Replies
Reply
Unknown
24 December 2021 at 20:59
Wow
Ẹ kú iṣẹ́ ọpọlọ
Reply
Delete
Replies
Reply
Add comment
Load more...
Newer Post
Older Post
Home
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Awesome! Please can you help me translate this to English.
ReplyDeleteWow
ReplyDeleteẸ kú iṣẹ́ ọpọlọ