Odo Yewa je odo ti o wa ni
orile ede Naijiria, odo yii pa ala laarin orile ede Naijiria ati ti Benin. Odo
yii je orisun eja pipa fun awon olugbe
agbegbe naa. Lara oun Pataki ti awon apeja agbegbe yii naa nri ninu odo yi ni
akan buluu ( Callinectes amnicola).Yato
si ise eja pipa odo yi tun wulo fun ise agbegilodo ati erupe wiwa. Orisun odo Yewa
meji ni odo atan ati odo ilaro. Odo Yewa san lo sinu odo Badagry Creek.
Awon ilu ti odo Yewa gba koja ni Atan,
Ilaro, Ado-odo, Apamu, Igunnu akabo, Badagry.
Odo Yewa san lo sinu okun Atlantic.
No comments:
Post a Comment