Odo Niger gba orile ede Guinea, Mali, Niger,Benin ati Naijiria
koja, odo Niger san sinu odo Sokoto, Kaduna, Benue ati Bani. Awon ilu ti odo
Naija gba koja ni Temba Kowida, Bamako, Timbuktu, Niamey, Lokoja ati Onitsha.
Orisun odo Niger ni awon Oke nla to wa ni
orile ede Guinea. Odo Niger si n san sinu okun Atlantic.
Ogun to kilomita 4,180. Odo nla ni odo naa
ni gbogbo iwo orun Afrika. Odo naa ni o peka wonu Niger Delta ni guusu Naijiria
ko to wonu okun Atlantic. Odo Niger ni odo to siketa ninu awon odo to tobi julo
niile Afrika. Odo Nile ati Congo ni awon odo meji ti won tobi juulo ni Afrika.
Oyinbo Mungo park ni kan ni amo le ni toti
la odo yi koja ri. Teletele ki Mungo Park to ola gbogbo odo yii ja, won o mo wi
pe odo naa logun de gbogbo ibi to de, odo Benue pade odo Naija ni Lokoja.
No comments:
Post a Comment