Monday, 3 October 2016

MARGI




          Won tun npe won ni Margi Central. O je ede Chad ti won nso lori le ede Naijiria. Won nso ni ipinle Borno ati Adamawa. Iye awon ti won nso le ni 160,000 eniyan ni odun 2006.

No comments:

Post a Comment