Awon eniyan to nso ede Tiv le ni milionu
metala ni orile ede Naijiria ati Cameroun.Awon to nso ede Tiv wa ni Benue,
Taraba, Nasarawa, Cross River, Plateau ati Abuja. Awon ara Tiv ni asa bi won ti
n joye. Awon oloye akoko ni won pe ni Tor.Awon oloye ni pele keji ni awon Ter.
Awon mejeeji ni won nsakoso ijoba ibile. Awon ipele oloye keta ni “Tyvor” awon
ni won nmojuto awon ipin kookan to wa labe ijoba ibile.
No comments:
Post a Comment