Monday, 3 October 2016

ISIKILU ONIKINIUN




      IsIkilu pinu ni ojo kan lati da ogba eranko sile. O ra ile ti eeka re po.Ona wo si, o si ni opolopo eranko ninu re. Ni gba tii o se tan, o polowo  fun awon eniyan lati maa wa si ogba eranko naa ki won si maa san egberun marun naira gege bi owo iwole. Ko ri eniyan kokan to wa. O din owo naa ku si egberun meji ati abo naira, sibe, ko ri eni kookan. Otun din owo naa
ku si egbe run kan aabo ko ri enikeni. O wa din owo naa ku si eedegbeta naira, si be ko ri enikeni.
     Owa pinu lati soodi ofe (free), awon ero wa yabo ibe biba, lati wa wo awon eranko.
      O ni suru fun gbogbo won lati wo le tan, won si wo awon eranko o te won lorun.Nigbatii ori  wi pe won setan o ti geeti ogba eranko mo gbogbo won. O wa tu kiniun sile wipe egberun lona ogun naira lohun maa gba lowo enikookan won fun wi wa ti won wa wo ogba ohun, lori ere ni awon eniyan bere si ni dagbogbo owo ti won ni sile, nitori wi pe ko si eni to fe ki kiniun fa oun ya.

No comments:

Post a Comment