IJAW
Awon ara
Ijaw je akojopo awon eniyan ti won wa lati ipinle Bayelsa, Delta ati Rivers ni
agbegbe Niger Delta ni orile ede Naijiria. Awon miiran ninu won ngbe ni Akwa Ibom,
Edo ati Ondo. Awon miran je awon apeja ton si kiri(migrant fishermen) ni awon
orile ede bi Sierra leone ati Gabon, ati awon ilu ti won wa ni eti bebe okun
iwo oorun Afirika. Ninu won ni idile Dakolo ti o wa lati ile Ghana, okan ninu
won to je gbajugbaja ni Timi Dakolo. Awon omo Ijaw le ni milionu mewa ni ye.
Are Orile ede Naijiria ana. Omowe Goodluck Jonathan je omobibi ilu Ijaw. Mesan
ni awon ede ibile to wa laarin awon ijo. Eyi to wopo ju ninu awon ede naa ni
Izon. Ede ti o te lee ni Kalabari. Oruko meji niwon mo awon ijo si ni igba
atijo, awon naa ni Kumoni tabi Oru. Idile lonaa aadota ni awon idile ipile ni
Ijaw
No comments:
Post a Comment