Ede yi je okan lara awon ede ni
Cameroun ti won nlo fun kara kata lorile ede Naijiria. Botileje pe iwonba awon die
ni awon to nso ede yi ni Cameroun, ati ni Naijiria. Ede naa ni won npe ni Jukun
Takum. Orisirisi eya ede losi wa labe ede yi, sugbon Jukun ni won fi ko gbogbo
won po.
No comments:
Post a Comment