YORUBAOLOJI
Sunday, 9 October 2016
AGBAJA
Agbaja ni agbegbe ibi ti won ti nwa irin tutu(iron ore) ni ipinle Kogi. Awon ara Oworo ni o ngbe ni Agbaja.
Agbaja naa ni olu ilu awon Oworo. Ilu yi wa lori oke, ti o sunmo ilu Abuja. Ilu yi ni irin tutu to po lopo yanturu.
No comments:
Post a Comment
Newer Post
Older Post
Home
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment