Ni abe Oyo
ni awon Egba wa laye atijo, Igbati ijoba Oyo dojubole ni igba Ogun Dahomey,
awon ara Egba ko farapa nitori won ri inu Olumo lati sa si, eleyii lo mu ki won
da ilu Abeokuta si le. Ipin marun ni Egba wa.
Awon ni Ake, Owu, Oke Ona, Gbagura ati
ibara.Ilu kookan ni won ni Ob ti won. Teletele merinni Egba pin si awon ni Ake,
Owu, Oke Ona ati gbagura.
Awon ara Yewa ni won je ara Ibara, sugbon tori
wi pe won sunmo Egba ni won se nka won mo Egba.
No comments:
Post a Comment