Ado Ekiti ati Osan Ekiti je
Ilu nla ni ile Yoruba, won tun maa n pee ni Ado. Won to 308,621
eniyan(2006). Won ni ile eko giga yunifasiti ni lu won ti o je ti ijoba, won si
ni eyi ti o je ti aladani(Afe Babalola University Ado Ekiti). Won tun ni ile
eko giga gbogbonise(Federal Polytechnic, Ado Ekiti) ile ise amohunmaworan meji
(NTA Ado Ekiti ati Ekiti State Television) won si ni ile ise redio meji(Redio
Ekiti ati Progress FM)
No comments:
Post a Comment