YORUBAOLOJI

Tuesday, 16 August 2016

ORIKI IBEJI



Ejire ara isokun 
Edunjobi
Omo edun tii sere
Ori igi reterete
Obekese bekasa
O fese mejeeji be sile 
Alakisa
O sa lakisa do ni gbaaso
Gbajumo omo tii gba dobale
lowo baba,
Tii gbakunle lowo 
mama to bii lomo
Wirinwirin loju orogun
Ejiworo loju iyaare
Posted by Opeifa Gabriel at 23:07
Email ThisBlogThis!Share to XShare to FacebookShare to Pinterest

No comments:

Post a Comment

Newer Post Older Post Home
Subscribe to: Post Comments (Atom)

Blog Archive

  • ▼  2016 (72)
    • ►  November (8)
    • ►  October (14)
    • ►  September (10)
    • ▼  August (24)
      • TOLOTOLO MO ENI TO NYIBON IDI SI
      • OLOJUKAN KI I TAKITI ORO
      • GBOLOHUN ONIBO
      • URHOBO –ISOKO
      • IBIBIO
      • GWARI
      • BIROM
      • ORIKI IBEJI
      • ORIKI IFE
      • ORIKI IYAN
      • Oriki awon Onikoyi
      • Kaka ki nbi egbaa obun
      • OJA ILU MI
      • ITELORUN LAGBA ORO
      • ERE IWANWARA (Consequence of hasty judgement)
      • AKI I PELU OBO JAKO (YOU DON’T JOIN THE MONKEY TO ...
      • ABANIJE (2)
      • IPA OGBE NI NSAN: (THE WOUND LEFT BY A CUTLASS MAY...
      • OGUN ILARA( BATTLE OF ENVY)
      • ISE TI EDO NSE LARA (FUNCTIONS OF THE LIVER)
      • Bi o jo ewure ba pe
      • ILE YORUBA
      • ODO YEWA
      • ODO NIGER
    • ►  July (12)
    • ►  June (4)

About Me

My photo
Opeifa Gabriel
View my complete profile
Travel theme. Powered by Blogger.