Tuesday 2 August 2016

ODO NIGER



                                                               


 Odo Niger gba orile ede Guinea, Mali, Niger,Benin ati Naijiria koja, odo Niger san sinu odo Sokoto, Kaduna, Benue ati Bani. Awon ilu ti odo Naija gba koja ni Temba Kowida, Bamako, Timbuktu, Niamey, Lokoja ati Onitsha.
     Orisun odo Niger ni awon Oke nla to wa ni orile ede Guinea. Odo Niger si n san sinu okun Atlantic.
    Ogun to kilomita 4,180. Odo nla ni odo naa ni gbogbo iwo orun Afrika. Odo naa ni o peka wonu Niger Delta ni guusu Naijiria ko to wonu okun Atlantic. Odo Niger ni odo to siketa ninu awon odo to tobi julo niile Afrika. Odo Nile ati Congo ni awon odo meji  ti won tobi juulo ni Afrika.
    Oyinbo Mungo park ni kan ni amo le ni toti la odo yi koja ri. Teletele ki Mungo Park to ola gbogbo odo yii ja, won o mo wi pe odo naa logun de gbogbo ibi to de, odo Benue pade odo Naija ni Lokoja.

No comments:

Post a Comment