Sunday 21 August 2016

GWARI




     Awon wonyi ni ara Gbagyi  tabi Gbari. Awon ni won wa ni aarin orile ede Naijiria. Won to milionu meedogun niye. Ede meji lo wa laarin won. awon Hausa ati awon Oyinbo alawo funfun ni won bere si ni pe won ni Gwari ni gba atijo, sugbon oruko ti o te awon gan an lorun ni Gbagyi. Won ngbe ni awon ipinle Niger, Kaduna ati Abuja, Nasarawa ati Kogi. Ise agbe ni won yan laayo.
     Oye oba won ni Osu. won tun sise ode, ise ikoko mi mo,odo ati omo odo sise.
Won po si kachia (Kaduna), Minna, Kwakuti, Kwali, Wushapa, Bwaya (Buhari), Suleja ati Paiko. Awon Ojogbon onitan kan gba wi pe ogun Jihadi awon Fulani lo tu won Kaakiri. Ijoba apapo lo le won kuro lori ile abinibi won, ti won so di ti igbalode.
     Awon niwon ni ori oke Zuma ti o di ti ijoba lo ni.Awon ara Gbagyi je eniyan tutu ti kii fa wahala. Ede meji ti won nso ni Gbari ati Gbagyi.

No comments:

Post a Comment