Tuesday, 26 July 2016

KINIUN



   

                                


            

 Kiniun je okan lara awon ologbo nla ninu igbo kijikiji. Awon ti won je ako ninu won maa nwon to kilo lona 250 nigba miiran.Ninu gbogbo eranko igbe ti o ti idile awon ologbo nla wa, kiniun ni eranko to sikeji ta ba n so titobi,  ekun lo tobi ju, kiniun lo tele e ni idile ologbo nla. Awon kiniun igbo si wa ni apakan ile afirika ati ni india. Ni igba
laelae a ma nri kiniun kaakiri opolopo ile afirika,ile yuroopu, ile giriki titi to fi de India. Ni igba kan ri, bi egberun  odun mewaa 10,000  seyin,kiniun je eranko-nla to poju lo leyin awon eniyan,sugbon loni won ko to nkan mo.
 Kiniun wa lara awon eranko ti a jo IUCN  so wipe oseese ki a padanu gbogbo won lai pe ti a ko ba  wa woroko fi sada lori awon nkan to npa won run. Okan lara nkan ti ko je ki won po mo ni  asa  sogbedigboro. Gbogbo igbo ti awon eranko wonyii  nraye fara pamo si  ni won ti fere so di lu tan. Oun keji ti ko je ki won tun  wopo ni, riri ti awon omo eniyan maa nri won gegebi eranko to le wu,nitori naa, won n pa won nipa  kupa. Paapaa julo eleyii yo awon kiniun to wa ni iwo oorun afirika lenu ju.
 Ninu igbo, ako kiniun kii loju odun mewaa si odun merinla  lo laye. Oun to tun bo maa nfa iku aitojo fun ako kiniun ni awon ipalara orisirisi ti won ti ni ni pa ija gbogbo igba  pelu awon ako egbe  won. Sugbon awon kiniun to ba wa ni ahamo ogba eranko le lo to ogun (20) odun laye.
     Won feran lati  maa gbe ninu papa, laarin awon koriko, sugbon atun maa nri awon miiran ni inu  igbo.


  Kiniun je eranko to nbegbe se, ofi abuda  yii da yato si gbogbo eranko yooku. Kiniun kii sa ba pa eniyan je, sugbon atiri awon ti won se be laarin won.

  Oorun ni kiniun maa nfi osan sun, asale tabi oru ganjo ni kiniun maa njade lo sode. Irun pupo tobo oju ni afi n da ako kiniun mo. Awon ebi kiniun to sunmo o julo ni ekun, amotekun, jagua ati amotekun yinyin. Imo sayensi fi  ye wa wi pe ile afirika ni kiniun ti se wa. Ibe loti  tan ka ibi gbogbo lagbaye. Imo  ijinle so fun wa wipe kiniun ti wa ni ile afirika lati odun milionu kan seyin.


  Orisi kiniun mejila (12) lo wa. Oun ti won fi yato sira won ni irun oju won, titobi won ati ilu ti a ti ri won.
 Ti kiniun ba ba abo ekun sun won maa n bi eya eyiti awon onimo sayensi n pe ni ligers ati tiglons. Ti a ba mu ako kiniun gun abo amotekun won yoo bi eyi ta n pe ni leopens. Ti a ba mu ako kiniun gun abo jagua won a bi jaglions. Marozi nikan ni kiniun ti o fi awo jo amotekun lai je wipe kiniun gun amotekun lati bii. Bo se maa n wa ye niyen. Kiniun kan naa wa ni ile Kongo to farajo amotekun ati jagua. Oruko re ni lijagulep.

                                     TIGLON

  Omo ti ako kiniun ati abo ekun' ba bi maa ntobi ju won lo.
  Bawo ni asele da ako kiniun yato si abo kiniun? abo kiniun kii ni irungbon, iru eyi ti ako ni kiniun maa n ni. Kiniun funfun naa wa.
Won kii se afin, nitori wipe eyin  oju won ni dudu ninu. Won wopo ni orile ede South Afirika.

                                        LEOPEN

     Kiniun kii lepa lati pa agba erin, turuku,gaseli imipala ati agbonrin to ba lagidi sugbon awon bi efon ati jirafu jije ni fun won. Ako kiniun ma nto omo odun meta, kato sope oti dagba.
 Bi kiniun ba tito omo odun mewaa si meedogun won ti dagba, yoo si ti maa re. Ko si eranko to le so wipe oun le pa agbalagba kiniun  sugbon, eyi toba  yaro ninu won ni pa ipalara le di ije fun awon eranko miiran .
 Eranko kansoso tole  seru ba kiniun ni oni naili(Nile Crocodile), kosi akoko ti kiniun ko le bimo ogorun ole  mewaa ojo 110, ni abo kiniun ma fi nru oyun re, leekannaa ole bi omo meta si merin. Nigba ti omo kiniun ba fi pe osu mokanla oun naa yoo bere  si ni sode eran pipa.

11 comments:

  1. Replies
    1. Yorubaoloji: Kiniun >>>>> Download Now

      >>>>> Download Full

      Yorubaoloji: Kiniun >>>>> Download LINK

      >>>>> Download Now

      Yorubaoloji: Kiniun >>>>> Download Full

      >>>>> Download LINK p3

      Delete
  2. nordvpn crack Thanks for this post, I really found this very helpful. And blog about best time to post on cuber law is very useful.

    ReplyDelete
  3. Advanced SystemCare Pro Crack The clients get 100% unique Microsoft permit that can be actuated straightforwardly on the authority Microsoft site. Besides, it offers a lifetime permit which demonstrates that it doesn't offer a membership administration and doesn't expect one to recharge it time for an expense.

    ReplyDelete
  4. I really like your content. Your post is really informative. I have learned a lot from your article and I’m looking forward to applying it in my article given below!.
    MainStage Crack
    The Foundry Nuke Studio crack
    Brave Browser crack
    Passmark BurnInTest Pro CrackPassmark BurnInTest Pro Crack

    ReplyDelete
  5. I am very thankful for the effort put on by you, to help us, Thank you so much for the post it is very helpful, keep posting such type of Article.
    DU Meter Crack
    Autodesk InfraWorks Crack
    ZWCAD Crack Free Download
    EditPlus Crack Free Download

    ReplyDelete