Ijanba
ina kan ti o sele loju mi waye ni ojo kerinla osu keji odun 2013. O wa ye ninu
soobu kan ni alaguntan, iyana ipaja. Soobu yi ko jina siibi ti ise mi wa. Soobu
naa wa ni abe ile alaja meta ti o do ju ko ilepo mobili ni alaguntan.
Sunday, 31 July 2016
Saturday, 30 July 2016
ERIN
Ounje :
won maa n je eweko, banbu eepo igi ati gbongbo igi. Won tun maa nje ireke,
ogede. Agbalagba lojumo.
Bonsepoto:
loni iye erin towa ni ile Africa ko ju 450000-700000 lo mo iye erin ti o wa ni
ile Asia ko ju 35000-40000 lo mo
Igba ibalopo:
Ni gba ojo lopo igba
Oyun nini:
Osu meji le logbon (22)
Iye omo tiwon
maanbi: Eyo kan (ibeji sowon. Omo ikoko won maa nwo to poun 200-250.
IWA: Amaa
ntowon erin maa nwa lagbolagbo ni. Abo to dagba julo lo maa n dari agbo, tabi
eyi to tobi julo .Agbo erin le je bi erin mejo si ogorun. Erin ni opolo
lopolopo.
Giga : Ako
erin maa ngba to ese bata marun si merinla. Awon abo won maa n kere si awon
ako.
Gigun: won
maa n gun to ogbon ese bata lati imu de iru.
Wiwon :
ako erin maa n won to poun 6000 -15000
Ojo aye won:
Erin maa nto aadorin (70) odun laye
Ayajo awon erin
lagbayei ojo kejila osu kejo lodoodun.
Orisi :
orisi erin meji lowa. Erin ile afrika ati erin ile Asia.
Oun idanimu:
Imu gigun erin ni a le fi daa mo. O ma imu yi min, ofin gbe omi o si fin gba
nkan mu
Eti erin :
erin ni eti o tobi, osi maa n lo lati dari gbigbona ati titutu ara re.
Iwa: won
feran lati maa gbe nitosi omi. Awon abo erin maa n gbe po ni
Eyin: erin
maa n ni eyin merindinlogun (26).
Iwulo : ni
aye atijo won nlo erin fun ogun jija. Titi di oni ni asia won nlo awon erin fun
ise sise. Osese fun erin lati se orisirisi ogbon nkan ti a ba iwo tan.
Aisan :
iwadi tifi han wipe erin maa n ni aisan iko fe lara o si maa n ko ran eniyan.S
ROGBODIYAN AKEKOO TO SELE LOJU MI
Rogbodiyan
akekoo to sele loju mi sele ni iwaju ile iwe giga ti LASU ni odun 2002. O wa ye
laarin omobinrin akekoo ile iwe lasu kan ati ogbeni soja kan. Won jo wo oko
akero kosta lati mile 2, nigba tii omoobinrin yii fee bo sile, o se si lati te
ogbeni soja yii mole, laimo nigba tii soja so fun un, oni oun ko moo mo soja si
fun ni igbati olooyi, omobinrin yi ko se
mini semeji o bu soja yi so ninu oko, se won de ti de iwaju ile-iwe won.
Tuesday, 26 July 2016
KINIUN
Kiniun je okan lara awon ologbo nla ninu igbo
kijikiji. Awon ti won
je ako ninu won maa nwon to kilo lona 250 nigba miiran.Ninu gbogbo eranko igbe ti o ti idile
awon ologbo nla wa, kiniun ni eranko to sikeji ta ba n so titobi, ekun lo tobi ju, kiniun lo tele e ni idile
ologbo nla. Awon kiniun igbo si wa ni apakan ile afirika ati ni india. Ni igba
ORI YEYE NI MOGUN TAI SE LOPO
Nii
igba lae lae Mogun je ibi ti won maa nfi awon odaran ponbele si laye atijo. Ni
be ni won maa nbe ori awon odaran si. Enikeni ti won ba mu esun re wa ba Oba laaye atijo, ti eleeri sigbe e wi pe o huwa odaran, ipaniyan, idigunjale, ifipa
banilopo,iru won ni won nberi
wo si Mogun.
Saturday, 16 July 2016
OLUSEGUN OBASANJO
Oloye Olusegun
Obasanjo ti a bi ni ojo karun osu keta odun 1937, je ogagun soja to ti fe
yinti. Won si je olori orile ede Naijiria lati odun 1999 titi di odun 2007. Won je
omo bibi ile Yoruba. Ise soja ni ise ti won se, ki won too wa se olori orile
ede won lee meji. Lakoko gege bi olori
ijoba ologun lati ojo ketala osu keji odun 1976 di ojo kinni osu kewa
odun 1979. Lele keji, gegebi are orile ede
Friday, 15 July 2016
OLUKO TI MO FERAN JU
Oruko oluko ti
mo feran julo ni Ogbeni
Ojuromi Oladele.Won je
omo bibi ilu eko.Won si je
Olukoni ni le eko girama awon obinrin ti o wa ni Agege.Lesini irole ti won da sile fun awon akeeko ni a ti pade. Won je
olukoni fun imo baoloji. Okan
ninu awon oree mi lo mu mi mo ni pa lesini naa. Oruko re ni olajube Ayobami.Oruko
ti won npe lesini naa ni gba naa ni mireku tuto.
Saturday, 9 July 2016
Oriki Awon Ijebu
ORIKI
AWON IJEBU
E e e e e e
e e e e
Awa niyin
eeyan, awon ode omo digbolugi
Awon niwon
maa nso pe ijebu oloriki
Iro
patapata niwon npa, eyin ijebu momo oriki baba teyin
Wonni boba wun jebu awun ni e ni winiwini
Bo ba wun
jebu awun ni e ni winiwini
E e mope
boba wun jebu afenire yooku sodun agemo.
Eyin omo
alagemo afiyi jo wini
Thursday, 7 July 2016
Ise loogun ise
Ise
loogun ise
Mura
sise ore e mi
Ise
la fi n de ni giga
Bi
ako ba re mi feyinti
Bi o
le laari, bi ako ba re ni gbekele
Atera
mo se e ni,
Iya
re le lowo lowo,
Baba
re le lesin leekan
Tuesday, 5 July 2016
ORE TI MO FERAN JU
Oruko ore ti mo feran julo ni Tope Adesiyun.
O je omo bibi ilu Akure. Omo idile oba ni ise. O je eniyan giga. Orewa
lokunrin. O mo oro so. Olorun si jogun ogbon fun. O loyaya, ara re si yomoyan. Pabanbari
re ni wi pe o je eniyan ti o ni feran olorun ti o si beru olorun tinutinu re.
Olooto eniyan ni. O feran nkan ti emi.
Monday, 4 July 2016
FAARI ASEJU
Faari
je oun ti a le pe ni ako sise, to je asa to wopo laarin awon odo ati
agunbaniro. Otun yato si oge sise, bakan naa won si wonnu ara won. O je asa
olaju ti awon odo maa n fe ko. Faari je asa ti o ma n farahan ninu ihuwasi, oro
siso, ara mimu, irinrinrin, lilo eya ara kan lona to tun yato. Opolopo igba
nifaari maa nje asa ti a ko wole nipa wiwo awokose awon ti a ro wipe won laju
juwa lo
Sunday, 3 July 2016
AYEYE ISILE KAN TI WON SE NI ADUGBO MI
Ajanaku
koja mori nkan firi, baba rerin ka so pa a rerin ni oro ile awo-ya-nu-wo ti
Adajo agba Ajisafe ko si adugbo wa, see won ni olowo see oun gbogbo tan, bii
ile naa tiri janran-janran to, osu merin pere ni won fi ko gbogbo re pari lati
ipile. Adugbo Bode Eleyele ni Surulere ni ile naa wa.
Won
ra ile ati ile po ni. ni adugbo wa. N se ni awaro wi pe won kan ma a tun ile
naa se, ti won si ma kun loda nitori ile naa kii se kekere sugbon oun to yawa
lenu nikete tawon to wa ni be ko kuro ni pe ari ti katakata budosa wo adugbo
wa, won wa lo si ojule karun-un won si
wo gbo ile alaja kan kale fin-in fin-in.
Subscribe to:
Posts (Atom)