Saturday 30 July 2016

ERIN

                                                                                

                                                              
         



Ounje : won maa n je eweko, banbu eepo igi ati gbongbo igi. Won tun maa nje ireke, ogede. Agbalagba lojumo.
Bonsepoto: loni iye erin towa ni ile Africa ko ju 450000-700000 lo mo iye erin ti o wa ni ile Asia ko ju 35000-40000 lo mo
Igba ibalopo: Ni gba ojo lopo igba
Oyun nini: Osu meji le logbon (22)
Iye omo tiwon maanbi: Eyo kan (ibeji sowon. Omo ikoko won maa nwo to poun 200-250.
IWA: Amaa ntowon erin maa nwa lagbolagbo ni. Abo to dagba julo lo maa n dari agbo, tabi eyi to tobi julo .Agbo erin le je bi erin mejo si ogorun. Erin ni opolo lopolopo.
Giga : Ako erin maa ngba to ese bata marun si merinla. Awon abo won maa n kere si awon ako.
Gigun: won maa n gun to ogbon ese bata lati imu de iru.
Wiwon : ako erin maa n won to poun 6000 -15000
Ojo aye won: Erin maa nto aadorin (70) odun laye
Ayajo awon erin lagbayei ojo kejila osu kejo lodoodun.
Orisi : orisi erin meji lowa. Erin ile afrika ati erin ile Asia.
Oun idanimu: Imu gigun erin ni a le fi daa mo. O ma imu yi min, ofin gbe omi o si fin gba nkan mu
Eti erin : erin ni eti o tobi, osi maa n lo lati dari gbigbona ati titutu ara re.
Iwa: won feran lati maa gbe nitosi omi. Awon abo erin maa n gbe po ni
Eyin: erin maa n ni eyin merindinlogun (26).
Iwulo : ni aye atijo won nlo erin fun ogun jija. Titi di oni ni asia won nlo awon erin fun ise sise. Osese fun erin lati se orisirisi ogbon nkan ti a ba iwo tan.
Aisan : iwadi tifi han wipe erin maa n ni aisan iko fe lara o si maa n ko ran eniyan.S

No comments:

Post a Comment