Apeere awon eto eko ti won le se agbateru re po,
to si lapeere. Bii idije ifagagbaga laarin awon akekoo ni ibile kookan (inter
school quiz competition) awon omo to ba gbegba oroke le gba eto eko ofe lowo
won(scholarship).
Awon alase won gan le pase
nkan bayii fun awon alaga won lati se, ki won si
Apeere oun miran ti mo tun
ri wi pe won file wulo fun eto eko ni sisi awon yara ibi ikawe (library) loruko
won si agbegbe won. Nipa si se irufe awon nkan bayii, awon ara ilu a ye foju buruku
wo won. Awon naa yoo nipa rere ti won nko lawujo won.
Opolopo igba ni awon ara ilu ati awon
sorosoro tipe wi pe ki won wo gi le egbe naa, ijoba gomina Fasola tile gbiyanju
lati se bee sugbon won ko rii se. kole rorun lati wo gi le egbe naa nitori wi
pe ofin lo gbe e kale. Eto ofin kii si
ya boro
No comments:
Post a Comment