Ago iwoye je ilu ni abe ibile ariwa Ijebu ni ipinle Ogun. O wa lara awon ilu ti ero po julo ni ipinle
Ogun. Ilu meje pataki lo wa ni Ago Iwoye. Awon ni Idode, Imere, Isamuro, Ibipe,
Imososi, Igan ati Imosu. Oruko oba won ni Oba Abdulrazak Adenugba. Oye Oba won
ni Ebumawe ti Ago-Iwoye. Ile eko giga yunifasiti ipinle Ogun wa ni Ago-Iwoye.
Won da ile iwe naa sile ni odun 1982.
Die lara awon eeyan
pataki ti o ti. Ilu yi jade ni
- Omoba Segun Adesegun, igbakeji gomina ana ti ipinle Ogun
- Ogbeni Olusola Ogundipe, oga patapata(o ti feyinti) fun awon ajo
awon elewon(NPS)
-Seneto Jubril Martins Kuye
-Brigadier Babafemi Ogundipe
Iye awon to ngbe ninu ilu yi le ni 120000