Mofimu ni ege tabi
fonran ti o kere julo ti o ni itumo ati
ise ti o n se ninu ede girama
Ti a ba for mofimu si we we ko le ni itumo.
Orisi mofiimu
1. Mofiimu ipile/adaduro
2. Mofiimu afarahe
Mofiimu ipile je mofiimu ti o da itumo ni. O le da duro lai
farahe mofiimu miiran. Ki ni itumo mo bi a ba fo si wewe. Bi apeere apa, ese,
ori, imu
Mofiimu afarahe: je eleyii ti ko le da duro. Won maa nlo
pelu mofimu adaduro Lati fi kun itumo ti iru mofiimu adaduro bee ni.
Orisi meta ni mofiimu afarahe to wa
1. Afomo ibere
2 . afomo Aarin
3. Afomo eyin
Apeere
Ipin si mofiimu ' akobata' ni
A-ko-bata
Ipin si mofiimu 'omoowo' ni
Omo-owo
Ipin si mofiimu 'atijeun' ni
Ati-jeun
This was so helpful
ReplyDeleteThanks for the help👌