Sagamu je ilu nla ni ipinle
Ogun. O si je Olu ilu fun ibile Sagamu. Ilu yi wa ni itosi odo ibu. Ilu yi ni
opolopo okuta ti won fin se simenti (limestone), eyi ti won nlo ni opolopo ile
ise. Ilu Sagamu ni ibi ti won nko obi(kolanut) to poju lo ni orile ede
Naijiria. Ilu yi wa laarin ilu eko ati ilu Ibadan. Ni be ni ile ekose isegun
oyinbo ti Olabisi Onabanjo wa. Eni ti o je Akarigbo Remo lowolowo ni Oba M.A.
Sonariwo. Lara awon ilu ti owa ninu Sagamu ni Simawa, Ijokun, Ewu-Oluwo,
Ijagba, Surulere, Isote, Sabo, Makun, Ajaka, Epe , Soyindo, Ogido. Okan lara
awon gbajugbaja omo Sagamu ni Adebayo Ogunlesi.
No comments:
Post a Comment