Friday, 18 November 2016

ORO AYALO




Oro ayalo ni oro ti a mu lati inu ede miiran wo inu ede kan lona ti bi a ti nko ati bi a ti npe yoo fi se regi pelu ede ti a ti fe loo.
 Lara awon ede ti Yoruba ti ya oro lo ni ede Geesi, Hausa, Larubawa, Faranse ati bee bee lo

ORISI ORO AYALO

1, Ti afetiya: awon wonyii ni oro ti a ya lo ni pa titele bi won ti pe oro naa ninu ede ti a ti ya. Bi apeere ; Esther ni Esita, table ni tebu, Moses ni Mosisi
2. Ti afojuya: awon wonyii ni oro ti a ya lo ni pa titele bi won ti ko sile ninu ede ti a ti ya won lo. Bi apeere: Andrew: Anderu, Esther: Esiteri, Driver; direfa

8 comments: