5, Ladugbo
Agege, Eko
12-03-2016
Ore mi
owon,
Idi
pataki ti mo fi ko leta yii si o ni lati salaye oun ti oju mi ri lori
rogbodiyan to sele ni gba ti awon adigunjale wa si adugbo mi ni oru ojo keta,
osu kerin odun yii. Mo ro wi pe alaafia ni o wa pelu gbogbo ebi re, gegebi emi
naa se wa nibiyi.
Goke oree mi, oye koo ba awon ti
ori ko yo ninu rogbodiyan naa gbegba ope ni o. Ni dede agogo mokanla ale ni
awon atilaawi won yi wo adugbo, won gbe oko molue meji wa. Iye awon ti won si
je mejidinlogbon. Won ko orisirisi awon irinse ati awon oun elo ologun, bi ibon
atamatase, ibon dobubareli, ibon eekefotisefun po rere, se oko gbagbe wipe ile
oloke ni ile wa, omu ki ororun lati ri gbogbo nkan ti o sele ni kedere.
Ni kete ti won de ni agbenuso
won ti gbe ero megafoonu senu, o ki awon ara adugbo, o se wa pele, o pe oruko ara re ni makalaki
omo eleja, o so wi pe idikansoso ti awon fi de bawa lalejo nilati wa gba
isakole awon ninu awon ibukun tolorun fun wa ladugbo wa, o si ro wa pe ka fowo
so wopo pelu awon, lati mu ki ise naa ju se fun awon lati se. O si so fun wa wi
pe awon mejidinlogbon ni iye awon ta won wa. Awon si wa de ba wa lalejo pelu
gbogbo oun ijagun igbalode ati ti ibile. Oni awon yoo ma kan lekun lati oju le si
ojule ki a ma se agidi rara.
O wa pase fun okan ninu won ti ope
oruko re ni Diboi wipe ki o fi irin tutu owo re powe di e fun wa, ki a le mo wi
pe kii se seresere, leekannaa ni abere si ni gbo kau, kau, kau, kau,kau, kau bi
ona ogun igba, iro awon ibon naa rin le domu domu bii gbati ogun abele de, mi o
ni paro tan e, nse ni mo to sara lai mo, nitori eru, o wa pase fun diboi ki o sin
mi naa, o so fun wa wipe eleyii ti okerejulo ninu awon irinse ti awon ko wa ni
a gboseewo yen. Oni boba wun wa ka pe awon soja ni jaji tabi awon olopaa ko
gberegbe wi pe ko si baba nla enikeni to le koju awon.
Awon ile olowo po ni adugbo wa, awon ni
afojusun won. Won gbo itanilolobo wipe awon kan gbe owo kongilato ti ijoba fun
won wa le. Won pin ara won si gbogbo ojule to wa ladugbo, won jalekun wole,
enikeni ti ko ba tete silekun won alu nilukulu, won yinbo fun awon miran lese.
Won ba awon iyawo ile ati olomoge sun. Bi obinrin ba ba won sagidi won a pe
arawon jo bii merin, marun lati baa sun.
Nigbatii olode waa maa fi de ni agogo
mejila ku ogun iseju, won ti fo le jina, won tin ko awon eru ati owo sinu
molue, ori loko olode wa yo wi pe orin tifura tifura. Oun naa lo pe awon olode
egbere to ku ati awon opisi kaakiri. Awon naa ba sigunde. Pelu oko danfo meji.
Nse ni adugbo wa di oju ogun lojo ti a wi
yi. Botile je wipe ibon tawon olode ko gbowo to ti awon ole yii, won ni awon
ogun buruku, abenugo lowo. Awon kan ninu awon ole nfole lo, beni awon kan ninu
awon ole toku doju ko awon olode ati opisi won yi. Won wa nro ota ibon lu ara
won ni kosekose. Ota ibon ko ran awon olodo beni awon ole nyera fun eyiti awon
olode nyin.
Bi wahala yi ti po to, ni oju le kewaa,
malamu Hausa kon wa ti osun ni wa ju ita ile re, ko tile bikita lati sa wole,
eru kobaa rara, ota ibon ko si baa. Okan
ninu awon ole yii ri ti on sun ni agbalaa re, agbala naa ni geeti. Ole yii ti
oruko re nje Diboi, binu sii, o mu igo, o si so igo si malamu naa, sugbon igo
naa haa si enu irin geeti naa, ko ba malamu yii, inu wa bi malamu naa wi pe oun
o da si won lataaro o, ki lode ti o waa nwaja oun. Omu epe senu osi pase fun
Diboi ko rin lo. Diboi is rinlo patapata. O rin lo fin in fin in.
Ninu rogbodiyan yi, ibon ti ba odo marun
ati alaboyun meji nibi ti won ti nsa kijo ki jo. Apa awon opiisi ko ka awon
olosa yi, nigba too ma fi di owo agogo meji aabo oru, agbo oun fere moto awon
olopaa, laipe won darapo mo awon opiisi lati dojuko awon olosa naa. Ogun naa le ore, nigbato maa fi di agogo
merin oku awon ole tidi mewaa nile, tawon opiisii ti di mejo, nigbati tawon
olopaa je meta.
Nigbati awon adingunjale rii wipe ota ntan lo
lowo won, won bere si ni sa lo leyo kookan. Won o le gbe awon moto molue won lo
mo, sugbon won ko gbe awon owo ti won ti ko sile, won nsalo leyoleyo, nigbatii
awon die ninu won si dojuko awon olopaa, kan maba bere sini le won. Awon to ku bere sini pariwo oruko Diboi, Diboi, Diboi,
eleyii ti malamu Hausa yen sepe fun ko rin lo, eleyii lotun mu kan pe, nitori
won o ri oku ati aaye Diboi. Awon olopaa tun pa meji si laarin awon toku,
nigbatii awon meji to ku feyin rin salo. Awon olopaa le won lo, nigbayen ni
awon aradugbo tu jade, pelu igbe lala, fun awon to loku nile, awon ti won ko
gbe eruwon bere si nii ko eru won, awon ti won ko owo won lo si bere sini gbera
sanle.
Nigbato ya iroyin so fun wa wipe owo
awon olopaa te gbogbo awon ole to ku naa, ile ejo sii dajo ewon gbere fun won.
Ore, aboori wipe rogbodiyan nla ni. Mo fe ko ba mi dupe lowo olorun.
Temi ni tire
Temitope
Wonderful! Keep it up.
ReplyDeleteThanks
DeleteGood , well, done ✅, beautiful
DeleteThis beautiful it really helped me construct my own
ReplyDeleteIt is okay.
ReplyDeleteI managed to use it to form my own.
It has helped me many times
Please oh translate and it is too long
ReplyDeleteVG
ReplyDeleteBeautiful 🥰❤️🥰🥰❤️❤️❤️
ReplyDeleteAwesome
ReplyDeleteYou are so rude
DeleteThanks for this 😍❤️❤️❤️❤️🥰🥰🥰
ReplyDeleteIt is to long and it is assignment form school
ReplyDeleteFoolish
ReplyDelete