5, Ladugbo
Agege, Eko
12-03-2016
Ore mi
owon,
Idi
pataki ti mo fi ko leta yii si o ni lati salaye oun ti oju mi ri lori
rogbodiyan to sele ni gba ti awon adigunjale wa si adugbo mi ni oru ojo keta,
osu kerin odun yii. Mo ro wi pe alaafia ni o wa pelu gbogbo ebi re, gegebi emi
naa se wa nibiyi.